2 Peter 3:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ẹ̀yin àyànfẹ́ mi, a ti kìlọ̀ fun yín tẹ́lẹ̀. Ẹ ṣọ́ra kí àwọn eniyan burúkú wọnyi má baà tàn yín sí inú ìṣìnà wọn, kí ẹ má baà ṣubú lórí ìpìlẹ̀ tí ẹ dúró sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ẹnyin olufẹ, bi ẹnyin ti mọ̀ nkan wọnyi tẹlẹ ẹ mã kiyesara, ki a má ba fi ìṣina awọn enia buburu fà nyin lọ, ki ẹ si ṣubu kuro ni iduro ṣinṣin nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ẹ́yín olùfẹ́, bí ẹ̀yin ti mọ nǹkan wọ̀nyí tẹ́lẹ̀, ẹ máa kiyé sára, kí a má baà fi ìsìnà àwọn ènìyàn búburú fà yín lọ, kí ẹ sì ṣubú kúrò ní ìdúró-ṣinṣin yín.