2 Samuel 1:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọrun Jonatani kì í pada lásán, bẹ́ẹ̀ ni idà Saulu kì í pada, láì fi ẹnu kan ẹ̀jẹ̀ àwọn tí ó pa, ati ọ̀rá àwọn akikanju.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrun Jonatani ki ipada, ati idà Saulu ki ipada lasan lai kan ẹjẹ awọn ti a pa, ati ọra awọn alagbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọrun Jónátánì kì í padà bẹ́ẹ̀ ni idà Ṣọ́ọ̀lù kì í padà lásán, láì kan ẹ̀jẹ̀ àwọn tí a pa, àti ẹran àwọn alágbára.