2 Samuel 10:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Hadadeseri ọba, bá ranṣẹ sí àwọn ará Siria tí wọ́n wà ní ìhà ìlà oòrùn odò Yufurate, wọ́n bá wá sí Helamu. Ṣobaki tí ó jẹ́ balogun àwọn ọmọ ogun Hadadeseri, ni aṣiwaju wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Hadareseri si ranṣẹ, o si mu awọn ara Siria ti o wà li oke odo jade wá: nwọn si wá si Helami; Ṣobaki olori ogun ti Hadareseri si ṣolori wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Hadadésérì sì ránṣẹ́, ó sì mú àwọn Síríà tí ó wà ní òkè odò jáde wá: wọ́n sì wá sí Hélámì; Sóbákì olórí ogun Hedareṣérì sì ṣe olórí wọn.