2 Samuel 10:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Dafidi gbọ́, ó rán Joabu ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀, láti lọ gbógun tì wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si gbọ́, o si rán Joabu, ati gbogbo ogun awọn ọkunrin alagbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì gbọ́, ó sì rán Jóábù, àti gbogbo ogún àwọn ọkùnrin alágbára.