2 Samuel 11:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, nígbà tí Joabu dóti ìlú Raba, ó rán Uraya lọ sí ibi tí ó mọ̀ pé àwọn ọ̀tá ti lágbára gidigidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe nigbati Joabu ṣe akiyesi ilu na, o si yàn Uria si ibi kan ni ibi ti on mọ̀ pe awọn alagbara ọkunrin mbẹ nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ṣe nígbà tí Jóábù ṣe àkíyèsí ìlú náà, ó sì yan Úráyà sí ibi kàn ní ibi tí òun mọ̀ pé àwọn alágbára ọkùnrin ń bẹ níbẹ̀.