2 Samuel 11:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun àwọn ọ̀tá jáde láti inú ìlú láti bá àwọn ọmọ ogun Joabu jà. Wọ́n pa ninu àwọn ọ̀gágun Dafidi, wọ́n sì pa Uraya ará Hiti náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọkunrin ilu na si jade wá, nwọn si ba Joabu jà: diẹ si ṣubu ninu awọn enia na ninu awọn iranṣẹ Dafidi; Uria ará Hitti si kú pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin ìlú náà sì jáde wá, wọ́n sì bá Jóábù jà: díẹ̀ sì ṣubú nínú àwọn ènìyàn náà nínú àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì, Ùráyà ará Hítì sì kú pẹ̀lú.