2 Samuel 11:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joabu bá ranṣẹ sí Dafidi láti ròyìn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ lójú ogun fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si ranṣẹ o si rò gbogbo nkan ogun na fun Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì ránṣẹ́ ó sì ro gbogbo nǹkan ogun náà fún Dáfídì.