2 Samuel 11:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó sọ fún oníṣẹ́ tí ó rán pé, “Bí o bá ti sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ lójú ogun fún ọba tán,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si paṣẹ fun iranṣẹ na pe, Nigbati iwọ ba si pari ati ma rò gbogbo nkan ogun na fun ọba,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì pàṣẹ fún ìránṣẹ́ náà pé, “Nígbà tí iwọ bá sì parí àti máa ro gbogbo nǹkan ogun náà fún ọba.