2 Samuel 11:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
inú lè bí i, kí ó sì bèèrè lọ́wọ́ rẹ pé, ‘Kí ló dé tí ẹ fi súnmọ́ ìlú náà tóbẹ́ẹ̀ láti bá wọn jà? Ẹ ti gbàgbé pé wọ́n lè bẹ̀rẹ̀ sí ta ọfà láti orí ògiri wọn ni?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ba ṣe pe, ibinu ọba ba fàru, ti on si wi fun ọ pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi sunmọ ilu na lati ba wọn jà, ẹnyin kò mọ̀ pe nwọn o tafà lati ori odi wá?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó bá ṣe pé, ibinú ọba bá fàru, ti òun sì wí fún ọ pé, ‘Èéṣe tí ẹ̀yin fí súnmọ́ ìlú náà láti bá wọn jà, ẹ̀yin kò mọ̀ pé wọn ó tafà láti orí odì wá.