2 Samuel 11:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tafàtafà bẹ̀rẹ̀ sí ta ọfà sí wa láti orí ògiri wọn, wọ́n sì pa ninu àwọn ọ̀gágun rẹ, wọ́n pa Uraya náà pẹlu.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn tafàtafa si ta si iranṣẹ rẹ lati ori odi wá, diẹ ninu awọn iranṣẹ ọba si kú, iranṣẹ rẹ Uria ará Hitti si kú pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tafàtafà sì ta sí ìránṣẹ́ rẹ láti orí odi wá, díẹ̀ nínú àwọn ìránṣẹ́ ọba sì kú, ìránṣẹ́ rẹ̀ Ùráyà ará Hítì sì kú pẹ̀lú.”