2 Samuel 11:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Uraya dé, Dafidi bèèrè alaafia Joabu ati ti gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀. Ó bèèrè bí ogun ti ń lọ sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Uria si de ọdọ rẹ̀, Dafidi si bi i li ere alafia Joabu, ati alafia awọn enia na, ati bi ogun na ti nṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Ùráyà sì dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, Dáfídì sì bi í léèrè báwo ni Jóábù ti ṣe àti àlàáfíà àwọn ènìyàn náà, àti bí ogun náà ti ń ṣe.