2 Samuel 12:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Natani bá lọ sí ilé rẹ̀. OLUWA fi àìsàn ṣe ọmọ tí aya Uraya bí fún Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Natani si lọ si ile rẹ̀. Oluwa si fi arùn kọlù ọmọ na ti obinrin Uria bi fun Dafidi, o si ṣe aisàn pupọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nátanì sì lọ sí ilé rẹ̀ OLÚWA sì fi àrùn kọlu ọmọ náà tí obìnrin Úráyà bí fún Dáfídì, ó sì ṣe àìsàn púpọ̀.