2 Samuel 12:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ó sì rán Natani wolii pé kí ó sọ ọmọ náà ní Jedidaya, nítorí pé, OLUWA fẹ́ràn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si rán Natani woli, o si pe orukọ rẹ̀ ni Jedidiah nitori ti Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì rán Nátanì wòlíì, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jédídíáyà, nítorí OLÚWA.