2 Samuel 12:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní gbogbo àkókò yìí, Joabu wà níbi tí ó ti gbógun ti Raba, olú ìlú àwọn ará Amoni, ó sì gba ìlú ọba wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si ba Rabba ti awọn ọmọ Ammoni jagun, o si gbà ilu ọba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì bá Rábà ti àwọn ọmọ Ámónì jagun, ó sì gba ìlú ọba wọn.