2 Samuel 12:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ranṣẹ sí Dafidi láti ròyìn fún un pé, “Mo ti gbógun ti Raba, mo sì ti gba ìlú tí orísun omi wọn wà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si ran awọn iranṣẹ si Dafidi, o si wipe, emi ti ba Rabba jà, emi si ti gbà ilu olomi wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì rán àwọn ìránṣẹ́ sí Dáfídì, ó sì wí pé, “Èmi ti bá Rábà jà, èmi sì ti gba àwọn ìlú olomi.