2 Samuel 12:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kó àwọn ọmọ ogun yòókù jọ, kí o kọlu ìlú náà, kí o sì gbà á fúnra rẹ. N kò fẹ́ gba ìlú náà kí ògo gbígbà rẹ̀ má baà jẹ́ tèmi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nitorina kó awọn enia iyokù jọ, ki o si do ti ilu na, ki o si gbà a, ki emi ki o má ba gbà ilu na, ki a ma ba pè e li orukọ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ nítorí náà kó àwọn ènìyàn ìyókù jọ, kí o sì dó ti ìlú náà, kí o sì gbà á, kí èmi má báà gba ìlú náà kí a má baà pè é ní orúkọ mi.”