2 Samuel 12:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi bá kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó lọ sí Raba, ó gbógun tì í, ó sì ṣẹgun rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si kó gbogbo enia na jọ, o si lọ si Rabba, o si ba a jà, o si gbà a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì kó gbogbo ènìyàn náà jọ, sí Rábà, ó sì bá a jà, ó sì gbà á.