2 Samuel 13:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Amnoni fẹ́ràn rẹ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó di àìsàn sí i lára. Wundia ni Tamari, kò tíì mọ ọkunrin rí; nítorí náà ó dàbí ẹni pé kò ṣeéṣe fún Amnoni láti bá a ṣe nǹkankan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Amnoni si banujẹ titi o fi ṣe aisan nitori Tamari aburo rẹ̀ obinrin; nitoripe wundia ni; o si ṣe ohun ti o ṣoro li oju Amnoni lati ba a ṣe nkan kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ámúnónì sì banújẹ́ títí ó fi ṣe àìsàn nítorí Támárì àbúrò rẹ̀ obìnrin; nítorí pé wúndíá ni; ó sì ṣe ohun tí ó ṣòro lójú Ámúnónì láti bá a dàpọ̀.