2 Samuel 13:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Dafidi ọba gbọ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀, inú bí i gidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati Dafidi ọba gbọ́ gbogbo nkan wọnyi, inu rẹ̀ bajẹ gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nígbà tí Dáfídì ọba gbọ́ gbogbo nǹkan wọ̀nyí, inú rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi.