2 Samuel 13:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Amnoni ní ọ̀rẹ́ kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jonadabu, ọmọ Ṣimea, ọ̀kan ninu àwọn arakunrin Dafidi. Jonadabu yìí jẹ́ alárèékérekè eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Amnoni ni ọrẹ́ kan, orukọ rẹ̀ a si ma jẹ Jonadabu, ọmọ Ṣimea ẹgbọ́n Dafidi: Jonadabu si jẹ alarekereke enia gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ámúnónì ní ọ̀rẹ́ kan, orúkọ rẹ̀ a sì máa jẹ́ Jónádábù, ọmọ Ṣíméà ẹ̀gbọ́n Dáfídì: Jónádábù sì jẹ́ alárékérekè ènìyàn gidigidi.