2 Samuel 14:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo sì ti mọ̀ lọ́kàn ara mi pé, ọ̀rọ̀ tí kabiyesi bá sọ fún mi yóo fi mí lọ́kàn balẹ̀ nítorí pé, ọba dàbí angẹli Ọlọrun tí ó mọ ìyàtọ̀ láàrin ire ati ibi. OLUWA Ọlọrun rẹ̀ wà pẹlu rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iranṣẹbinrin rẹ si wipe, Njẹ ọ̀rọ ọba oluwa mi yio si jasi itùnu: nitori bi angeli Ọlọrun bẹ̃ ni oluwa mi ọba lati mọ̀ rere ati buburu: Oluwa Ọlọrun rẹ yio si wà pẹlu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ sì wí pé, ‘Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ ọba OLÚWA mi yóò sì jásí ìtùnú; nítorí bí ańgẹ́lì Ọlọ́run bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA mi ọba láti mọ rere àti búburú: OLÚWA Ọlọ́run rẹ yóò sì wà pẹ̀lú rẹ.’ ”