2 Samuel 15:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn èyí, Absalomu wá kẹ̀kẹ́ ogun kan, ati àwọn ẹṣin, ati aadọta ọkunrin tí wọn yóo máa sáré níwájú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe lẹhin eyi, Absalomu si pèse kẹkẹ́ ati ẹṣin fun ara rẹ̀, ati adọta ọmọkunrin ti yio ma sare niwaju rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yin èyí náà, Ábúsálómù sì pèṣè kẹ̀kẹ́ àti ẹsin fún ara rẹ̀, àti àádọ́ta ọmọkùnrin tí yóò máa sáré níwájú rẹ̀.