2 Samuel 15:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Absalomu rán iṣẹ́ àṣírí sí gbogbo ẹ̀yà Israẹli, ó ní, “Tí ẹ bá gbọ́ tí wọ́n fọn fèrè, kí ẹ sọ pé, ‘Absalomu ti di ọba ní Heburoni.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Absalomu rán amí sarin gbogbo ẹyà Israeli pe, Nigbati ẹnyin ba gbọ́ iró ipè, ki ẹnyin si wipe, Absalomu jọba ni Hebroni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ábúsálómù rán àmì sáàrin gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì pé, “Nígbà tí ẹ̀yin bá gbọ́ ìró ìpè, kí ẹ̀yin sì wí pé, ‘Ábúsálómù jọba ní Hébúrónì.’ ”