2 Samuel 15:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Igba ọkunrin ni Absalomu pè, tí wọ́n sì bá a lọ láti Jerusalẹmu. Wọn kò ní èrò ibi lọ́kàn, ní tiwọn, wọn kò sì mọ ohun tí ó wà lọ́kàn Absalomu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igba ọkunrin si bá Absalomu ti Jerusalemu jade, ninu awọn ti a ti pè; nwọn si lọ ninu aimọ̀kan wọn, nwọn kò si mọ nkankan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Igba ọkùnrin sì bá Ábúsálómù ti Jérúsálẹ́mù jáde, nínú àwọn tí a ti pè; wọ́n sì lọ nínú àìmọ̀kan wọn, wọn kò sì mọ nǹkankan.