2 Samuel 15:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Oníṣẹ́ kan wá ròyìn fún Dafidi pé, “Ọkàn gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ti ṣí sí ọ̀dọ̀ Absalomu.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnikan si wá rò fun Dafidi pe, Ọkàn awọn ọkunrin Israeli ṣi si Absalomu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnìkan sì wá rò fún Dáfídì pé, “Ọkàn àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì ṣí sí Ábúsálómù.”