2 Samuel 15:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ọba ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ ti ń jáde kúrò ní ìlú, wọ́n dúró níbi ilé tí ó wà ní ìpẹ̀kun ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si jade, gbogbo enia si tẹle e, nwọn si duro ni ibikan ti o jina.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sì jáde, gbogbo ènìyàn sì tẹ̀lé e, wọ́n sì dúró ní ibìkan tí ó jìnnà.