2 Samuel 16:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ọba ati àwọn eniyan rẹ̀ yóo fi dé ibi odò Jọdani, ó ti rẹ̀ wọ́n, nítorí náà, wọ́n sinmi níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba, ati gbogbo awọn enia ti o mbẹ lọdọ rẹ̀ si wá ti awọn ti ãrẹ̀, nwọn si simi nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba, àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ó ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ sì dé Jódánì, ó sì rẹ̀ wọ́n, wọ́n sì sinmi níbẹ̀.