2 Samuel 16:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Absalomu ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ wọ Jerusalẹmu lọ, Ahitofeli sì wà pẹlu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Absalomu ati gbogbo awọn enia, awọn ọkunrin Israeli si wá si Jerusalemu, Ahitofeli si wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ábúsálómù àti gbogbo àwọn ènìyàn, àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sì wá sí Jérúsálẹ́mù, Áhítófélì sì wà pẹ̀lú rẹ̀.