2 Samuel 16:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n bá pàgọ́ kan fún Absalomu, lórí òrùlé ààfin, ó wọlé lọ bá àwọn obinrin baba rẹ̀ lójú gbogbo àwọn eniyan, ó sì bá wọn lòpọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si tẹ agọ kan fun Absalomu li orile; Absalomu si wọle tọ awọn obinrin baba rẹ̀ li oju gbogbo Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tẹ́ àgọ́ kan fún Ábúsálómù ní òrùlé; Ábúsálómù sì wọlé tọ àwọn obìnrin baba rẹ̀ lójú gbogbo Ísírẹ́lì.