2 Samuel 16:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọba bá sọ fún Siba pé, “Gbogbo ohun tí ó jẹ́ ti Mẹfiboṣẹti di tìrẹ láti ìsinsìnyìí lọ.” Siba sọ fún ọba pé, “Kabiyesi, mo júbà, jọ̀wọ́, jẹ́ kí n máa bá ojurere rẹ pàdé nígbà gbogbo.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si wi fun Siba pe, Wõ, gbogbo nkan ti iṣe ti Mefiboṣeti jẹ tirẹ. Siba si wipe, Mo tũba, jẹki nri ore-ọfẹ loju rẹ, oluwa mi, Ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sì wí fún Síbà pé, “Wò ó, gbogbo nǹkan tí í ṣe ti Mefíbóṣétì jẹ́ tìrẹ.” Ṣíbà sì wí pé, “Mo túúbá, jẹ́ kí n rí ore-ọ̀fẹ́ lójú rẹ, OLÚWA mi ọba.”