2 Samuel 17:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, Ahitofeli wí fún Absalomu pé, “Jẹ́ kí n ṣa ẹgbaafa (12,000) ninu àwọn ọmọ ogun, kí n sì bẹ̀rẹ̀ sí lépa Dafidi lọ lálẹ́ òní.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AHITOFELI si wi fun Absalomu pe, Emi o si yan ẹgbãfa ọkunrin emi o si dide, emi o si lepa Dafidi li oru yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhítófélì sì wí fún Ábúsálómù pé, “Èmi ó yan ẹgbàáfà ọkùnrin èmi ó sì dìde, èmi ó sì lépa Dáfídì lóru yìí.