2 Samuel 17:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Dafidi dé Mahanaimu, Ṣobi, ọmọ Nahaṣi, wá pàdé rẹ̀, láti ìlú Raba, ní ilẹ̀ Amoni. Makiri, ọmọ Amieli, náà wá, láti Lodebari; ati Basilai, láti Rogelimu, ní ilẹ̀ Gileadi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati Dafidi si wá si Mahanaimu, Ṣobi ọmọ Nahaṣi ti Rabba ti awọn ọmọ Ammoni, ati Makiri ọmọ Ammieli ti Lodebari, ati Barsillai ara Gileadi ti Rogelimu,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Dáfídì sì wá sí Mahánáímù, Ṣóbì ọmọ Nahásì ti Rábà tí àwọn ọmọ Ámónì, àti Mákírì ọmọ Ámíélì ti Lodebárì, àti Básíláì ará Gílíádì ti Rógélímù.