2 Samuel 18:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi kó gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó pín wọn ní ọgọọgọrun-un (100) ati ẹgbẹẹgbẹrun (1,000), ó fi balogun kọ̀ọ̀kan ṣe olórí ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
DAFIDI si kà awọn enia ti mbẹ lọdọ rẹ̀, o si mu wọn jẹ balogun ẹgbẹgbẹrun, ati balogun ọrọrun lori wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì ka àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì mú wọn jẹ balógun ẹgbẹgbẹ̀rún, àti balógun ọrọrún lórí wọn.