2 Samuel 18:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ogun Dafidi rí i, ó bá lọ sọ fún Joabu pé òun rí Absalomu tí ó ń rọ̀ lórí igi Oaku.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkunrin kan si ri i, o si wi fun Joabu pe, Wõ, emi ri Absalomu rọ̀ lãrin igi pọ́nhan kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkùnrin kan sì rí i, ó sì wí fún Jóábù pé, “Wò ó, èmi rí Ábúsálómù so rọ̀ láàrin igi óákù kan.”