2 Samuel 18:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mẹ́wàá ninu àwọn ọdọmọkunrin tí wọn ń ru ihamọra Joabu bá yí Absalomu po, wọ́n sì ṣá a pa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọdọmọdekunrin mẹwa ti ima ru ihamọra Joabu si yi Absalomu ka, nwọn si kọlù u, nwọn si pa a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀dọ́mọdékùnrin mẹ́wàá tí ó máa ń ru ìhámọ́ra Jóábù sì yí Ábúsálómù ká, wọ́n sì kọlù ú, wọ́n sì pa á,