2 Samuel 18:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ahimaasi, ọmọ Sadoku bá sọ fún Joabu pé, “Jẹ́ kí n sáré tọ ọba lọ, kí n sì fún un ní ìròyìn ayọ̀ náà, pé OLUWA ti gbà á lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahimaasi ọmọ Sadoku si wipe, Jẹ ki emi ki o sure nisisiyi, ki emi ki o si mu ihìn tọ̀ ọba lọ, bi Oluwa ti gbẹsan rẹ̀ li ara awọn ọta rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhímásì ọmọ Sádókù sì wí pé, “Jẹ́ kí èmi ó súré nísinsin yìí, kí èmi sì mú ìhìn tọ ọba lọ, bí OLÚWA ti gbẹ̀san rẹ̀ lára àwọn ọ̀ta rẹ̀.”