2 Samuel 18:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joabu bá sọ fún ọ̀kan ninu àwọn ará Kuṣi pé, “Lọ sọ ohun tí o rí fún ọba.” Ará Kuṣi náà bá tẹríba fún Joabu, ó sì sáré lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si wi fun Kuṣi pe, Lọ, ki iwọ ki o rò ohun ti iwọ ri fun ọba. Kuṣi si wolẹ fun Joabu, o si sare.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì wí fún Kúṣì pé, “Lọ, kí ìwọ ro ohun tí ìwọ rí fún ọba.” Kúṣì sì wólẹ̀ fún Jóábù ó sì sáré.