2 Samuel 18:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Ahimaasi ṣá tẹnu mọ́ ọn pé, “N kò kọ ohunkohun tí ó lè ṣẹlẹ̀, jọ̀wọ́ jẹ́ kí n sáré tẹ̀lé ará Kuṣi náà lọ.” Joabu bi í pé, “Kí ló dé tí o fi fẹ́ lọ, ọmọ mi? Kò sí èrè kankan fún ọ níbẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahimaasi ọmọ Sadoku si tun wi fun Joabu pe, Jọwọ, bi o ti wu ki o ri, emi o sare tọ Kuṣi lẹhin. Joabu si bi i pe, Nitori kini iwọ o ṣe sare, ọmọ mi, iwọ kò ri pe kò si ihìn rere kan ti iwọ o mu lọ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áhímásì ọmọ Sádókù sì tún wí fún Jóábù pé, “Jọ̀wọ́, bí ó ti wù kí ó rí, èmi ó sáré tẹ Kúṣì lẹ́yìn.” Jóábù sì bi í pé, “Nítorí kín ni ìwọ ó ṣe sáré, ọmọ mi, ìwọ kò ri pé kò sí ìhìn rere kan tí ìwọ ó mú lọ.”