2 Samuel 18:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ará Kuṣi náà dé, ó sì wí fún ọba pé, “Ìròyìn ayọ̀ ni mo mú wá fún oluwa mi, ọba! Nítorí pé, OLUWA ti fún ọ ní ìṣẹ́gun lónìí lórí gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ pa ọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si wõ, Kuṣi de; Kuṣi si wi pe, Ihin rere fun oluwa mi ọba: nitoriti Oluwa ti gbẹsan rẹ loni lara gbogbo awọn ti o dide si ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sì wò ó, Kúṣì sì wí pé, “Ìhìnrere fún OLÚWA mi ọba: nítorí tí OLÚWA ti gbẹ̀san rẹ lónìí lára gbogbo àwọn tí ó dìde sí ọ.”