2 Samuel 18:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba bi í pé, “Ṣé alaafia ni Absalomu, ọmọ mi wà?” Ará Kuṣi náà dáhùn pé, “Kí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí Absalomu ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ, ati gbogbo àwọn tí wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si bi Kuṣi pe, Alafia kọ Absalomu ọdọmọdekunrin na wà bi? Kuṣi si dahun pe, Ki awọn ọta oluwa mi ọba, ati gbogbo awọn ti o dide si ọ ni ibi, ri bi ọdọmọdekunrin na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sì bi Kúṣì pé, “Àlàáfíà kọ́ Ábúsálómù ọ̀dọ́mọdékùnrin náà wá bí?” Kúṣì sì dáhùn pe, “Kí àwọn ọ̀ta OLÚWA mi ọba, àti gbogbo àwọn tí ó dìde sí ọ ní ibi, rí bí ọ̀dọ́mọdékùnrin náà.”