2 Samuel 18:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó pàṣẹ fún Joabu, ati Abiṣai, ati Itai, ó ní, “Nítorí tèmi, ẹ má pa Absalomu lára.” Gbogbo àwọn ọmọ ogun sì gbọ́ nígbà tí Dafidi ń pa àṣẹ yìí fún àwọn ọ̀gágun rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si paṣẹ fun Joabu ati Abiṣai ati Ittai pe, Ẹ tọju ọdọmọkunrin na Absalomu fun mi. Gbogbo awọn enia na si gbọ́ nigbati ọba paṣẹ fun gbogbo awọn balogun nitori Absalomu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sì pàṣẹ fún Jóábù àti Ábíṣáì àti Ítaì pé, “Ẹ tọ́jú ọ̀dọ́mọkùnrin náà Ábúsálómù fún mi.” Gbogbo àwọn ènìyàn náà sì gbọ́ nígbà tí ọba pàṣẹ fún gbogbo àwọn balógun nítorí Ábúsálómù.