2 Samuel 18:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun náà bá jáde lọ sinu pápá láti bá àwọn ọmọ ogun Israẹli jà, ní aṣálẹ̀ Efuraimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia na si jade lati pade Israeli ni pápá; ni igbó Efraimu ni nwọn gbe pade ijà na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn náà sì jáde láti pàdé Ísírẹ́lì ní pápá; ní igbó Éfúráímù ni wọ́n gbé pàdé ijà náà.