2 Samuel 18:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun Dafidi ṣẹgun àwọn ọmọ ogun Israẹli. Wọ́n pa wọ́n ní ìpakúpa ní ọjọ́ náà. Àwọn tí wọ́n kú lára wọn jẹ́ ọ̀kẹ́ kan (20,000).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nibẹ li a gbe pa awọn enia Israeli niwaju awọn iranṣẹ Dafidi, ọ̀pọlọpọ enia lo ṣubu li ọjọ na, ani ẹgbãwa enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ni a gbé pa àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì níwájú àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ó ṣubú lọ́jọ́ náà, àní ẹgbàáwá ènìyàn.