2 Samuel 18:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogun náà tàn káàkiri gbogbo agbègbè; àwọn tí wọ́n sì sọnù sinu igbó pọ̀ ju àwọn tí wọ́n fi idà pa lójú ogun lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogun na si fọ́n ka kiri lori gbogbo ilẹ na: igbógàn na si pa ọ̀pọ enia jù eyi ti idà pa lọ li ọjọ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ogun náà sì fọ́n káàkiri lórí gbogbo ilẹ̀ náà: igbó náà sì pa ọ̀pọ̀ ènìyàn ju èyí tí idà pa lọ lọ́jọ́ náà.