2 Samuel 19:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ìṣẹ́gun ọjọ́ náà pada di ìbànújẹ́ fún gbogbo àwọn eniyan; nítorí wọ́n gbọ́ pé ọba ń ṣọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iṣẹgun ijọ na si di awẹ̀ fun gbogbo awọn enia na, nitori awọn enia na gbọ́ ni ijọ na bi inu ọba ti bajẹ nitori ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìṣẹ́gun ijọ́ náà sì di ààwẹ̀ fún gbogbo àwọn ènìyàn náà, nítorí àwọn ènìyàn náà gbọ́ ní ijọ́ náà bí inú ọba ti bàjẹ́ nítorí ọmọ rẹ̀.