2 Samuel 19:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó lọ pa irọ́ mọ́ mi lọ́dọ̀ ọba. Ṣugbọn bí angẹli Ọlọrun ni oluwa mi, ọba rí; nítorí náà, ṣe ohun tí ó bá tọ́ sí mi ní ojú rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si sọ̀rọ ibajẹ si iranṣẹ rẹ, fun oluwa mi ọba, ṣugbọn bi angeli Ọlọrun li oluwa mi ọba ri: nitorina ṣe eyi ti o dara loju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí ìránṣẹ́ rẹ, fún OLÚWA mi ọba, ṣùgbọ́n bí áńgẹ́lì Ọlọ́run ni OLÚWA mi ọba rí: nítorí náà ṣe èyí tí ó dára lójú rẹ.