2 Samuel 2:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Joabu bá fọn fèrè ogun, láti fi pe àwọn eniyan rẹ̀ pada. Nígbà náà ni wọ́n tó pada lẹ́yìn àwọn eniyan Israẹli, tí wọ́n sì dáwọ́ ogun dúró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si fún ipè, gbogbo enia si duro jẹ, nwọn kò si lepa Israeli mọ, bẹ̃ni nwọn kò si tun jà mọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì fọ́n ipè, gbogbo ènìyàn sì dúró jẹ́ẹ́, wọn kò sì lépa Ísírẹ́lì mọ́, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò sì tún jà mọ́.