2 Samuel 20:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí ó wọ́ ọ kúrò lójú ọ̀nà tán, gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí sá tẹ̀lé Joabu, wọ́n ń lépa Ṣeba lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o si gbe e kuro li oju ọ̀na, gbogbo enia si tọ̀ Joabu lẹhin lati lepa Ṣeba ọmọ Bikri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó sì gbé e kúrò lójú ọ̀nà gbogbo ènìyàn sì tọ Jóábù lẹ́yìn láti lépa Ṣébà ọmọ Bíkírì.