2 Samuel 20:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá pada lẹ́yìn Dafidi, wọ́n tẹ̀lé Ṣeba. Ṣugbọn àwọn eniyan Juda tẹ̀lé Dafidi, ọba wọn, pẹlu ẹ̀mí òtítọ́, láti odò Jọdani títí dé Jerusalẹmu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ọkunrin Israeli si lọ kuro lẹhin Dafidi, nwọn si ntọ Ṣeba ọmọ Bikri lẹhin: ṣugbọn awọn ọkunrin Juda si fi ara mọ́ ọba wọn lati odo Jordani wá titi o fi de Jerusalemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sì lọ kúrò lẹ́yìn Dáfídì, wọ́n sì ń tọ́ Ṣébà ọmọ Bíkírì lẹ́yìn: ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin Júdà sì fi ara mọ́ ọba wọn láti odò Jódánì wá títí ó fi dé Jérúsálẹ́mù.