2 Samuel 20:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Joabu ni balogun àwọn ọmọ ogun ní Israẹli. Bẹnaya ọmọ Jehoiada sì ní olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joabu si li olori gbogbo ogun Israeli: Benaiah ọmọ Jehoiada si jẹ olori awọn Kereti, ati olori awọn Peleti:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jóábù sì ni olórí gbogbo ogun Ísírẹ́lì: Bénáyà ọmọ Jéhóiádà sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì, àti ti àwọn Pélétì.